Alaafia/Kosemanih tv

Alaafia/Kosemanih tv Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Alaafia/Kosemanih tv, Grocers, Lagos.

02/07/2026

Health/beauty

02/07/2026

OGUN AYETA, IbonTI O DAJU

EPA TO LOMO META KAN
ESO WERENJEJE EYOKAN
Ao wa epa tutu ti o ni omo meta ninu ,ao yo ti aarin inu epa naa , a o gbemin , ao wa fi eso werenjeje kan si aye ti o sofo ninu epa naa , a o wa gbe.sinu ,owu akese ti yio bo gbogbo ara re patapata, a o wa we ni owu dudu ati funfun, ao wa ranlawo, a o ma fi si ara jade , hmmmm ogun ayeta ibon todaju ni, amon Oluwa daju ju belo✅

Fun diabetes ati ifunpa giga ati ki atelese oma ku ririEWE Grover.Alubosa ayu.Alubosa onisu.ERU ALAMO. Aogun PAPO,Pandor...
22/06/2026

Fun diabetes ati ifunpa giga ati ki atelese oma ku riri

EWE Grover.
Alubosa ayu.
Alubosa onisu.
ERU ALAMO.
Aogun PAPO,
Pandoro ODIDI tele agbo
Aowase LAGBO TIO JINNA DADA, omire laofi se onje boya Amala, tabi semo, abi eba, abi rice je✅

AGBO FUN GBOGBONISE•Jedijedi•Aikori Orun sun•Pajapaja Owo/Ese•Arun Ibalopo (STI)•Low Cholesterol •Ifunpa GIGA (High Bloo...
28/04/2026

AGBO FUN GBOGBONISE
•Jedijedi
•Aikori Orun sun
•Pajapaja Owo/Ese
•Arun Ibalopo (STI)
•Low Cholesterol
•Ifunpa GIGA (High Blood Pressure)
•Ito Atoju (Frequent Urination)

Ewe yi ni anpe ni EWE EYINOLOBE
Agbo yi dara fun Eyikeyi Awon Ipenija Tabi Aisan ti o ba ndamu Eniyan Ninu ago Ara, iwadi Imo Ijinle je ki o yewa wipe, Ewe yi ni awon Oniruru Eronja Afara lokun, bakana a tun ma mun Adinku ba Eyikeyi Irora Ninu ago Ara.

BI AO SESE
Ao ja Ewe yi ni Tutu Tegbotegbo, ao fo nu ki o mo dada, ao ao SE ki o jina fun bi Ogbon iseju.

Mimu ni stainless cup kan ni owuro ati Ale

Iwo na Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran na ki won o le baje Anfani re!

Gbogbo wa konifi Aisan Logba oo 🙏 .
.
.

Dear TTC mom congratulations if you can see this post.Guava leaf Aidan fruit Boil everything together Drink a glass morn...
30/01/2026

Dear TTC mom congratulations if you can see this post.

Guava leaf
Aidan fruit

Boil everything together

Drink a glass morning and night for 7 days

It's help clean and flush everything dirty in
Ur womb.




You can last between 45 to an hour if you want to. Get 2 bitter cola, ginger and coconut water. Crush the bitter cola an...
22/01/2026

You can last between 45 to an hour if you want to. Get 2 bitter cola, ginger and coconut water. Crush the bitter cola and the ginger or you can grind them. Mix with coconut water and drink. Wait for about 30 to 40 minutes before tatata.

Stay healthy in Nigeria✅

15/01/2026
 .
24/09/2025

.

AGBO AKO JEDI / NKAN FUFUNTI O NJADE LOJU ARA OBINRIN(WHITISH DISCHARGE)========================Ki nkan funfun o ma jade...
18/09/2025

AGBO AKO JEDI / NKAN FUFUN
TI O NJADE LOJU ARA OBINRIN
(WHITISH DISCHARGE)
========================
Ki nkan funfun o ma jade Loju ara Obinrin kotumosi pe Eni na ni Arun Infection rara ni igbamiran.
Opo obinrin ni won ti lo oniruru ogun infection ti won Lero pe Arun infection ni Awon ni sugbon ti kosi ri be rara.

Lotito Ati lododo,Nkan funfun le majade loju ara Obinrin Ki o si jepe Arun infection ni sugbon oni apere ti yi o bade bee na sini oni Asiko pelu.

Ti Obinrin ba nri nkan funfun loju ara ti o si jepe nkan funfun na o san (Thinner) ni akoko ti o nsunmo Ovulation ni asiko ti o ba sese pari nkan osu re,

Bakana,ti obinrin ba n ovulate lo wo, Osese Ki o Mari Apere Nkan funfun ti o kii (Thick) ju ti akoko yen lo.

Ti Obinrin ba nri iru Awon Apere won yi Awon Apere ti o da gidi ni.

SUGBON ti Awon Apere yi bati Yato si Awon ohun ti a ka sile yi, a je wipe Arun INFECTION ni yen.
Arun INFECTION yi si pin si Awon ona ti o po.

AWON OHUN TI AO WA
==================
Ewe Ajanrere Tutu
Bara Nla Odidi kan
Omidun yangan
Kahun bulala die

BI AO SESE
=========
Ao fo gbogbo e Pelu omi ti o mo dada,Ao da gbogbo e Sinu pot,ao da Omidun yen lelori,ao se ti o jina dada fun bi Ogbon iseju (30min),ao se (Filter).
Ao ro Sinu Ike ti o ba mo,a le gbe pamo sinu fridge

LILO RE
======
Ao ma mu ni Idaji stainless cup ni ojo meta meta

Mogba ladura pe Gbogbo wa o nifi Aisan Logba ooooo 🙏🙏

Fun ibere
#+2348057702533.

Tongue indications for Health problems⚓
31/07/2025

Tongue indications for Health problems⚓

Address

Lagos

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 09:00 - 17:00

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Alaafia/Kosemanih tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category