Orioke Erioba Alasepe

Orioke Erioba Alasepe KI ILE ONI TO SU ERI AYO MA TI WO AYE RE

23/07/2026
23/07/2026

MORING MERCY PRAYER ADURA ANU OWURO
Mercy of God will locate your life today

God will send you good helps to help you to bay all your bills today

God will speak good mercy to end your sorrow for you today

Please share this prayer to all group on your Facebook

Bible Verses for this prayer morning
Plsam 23 :6
Hebrew 4:16
Plsam 103:8

Olorun alanu sanu fun gbogbo eniyan to ba adura yi pade

Oluwa ko gbe iranlowo anu ati oju rere dide si ile aye re loni

Anu Olorun yio si waju re ni gbogbo ibi to ba fi ese re te loni

Gbogbo ibi ti ogbon ori re ti pari je ki anu olorun ko dide si ile aye re ni ibe ni oruko Jesu

Anu Olorun yio fa igi le gbogbo ete ota buburu ni waju re loni loruko Jesu

Oluwa ko fi owo agbara ati anu re se itusile aye re niun ide aisan loni

Oluwa so fun mi wipe oni re yio dara ju bi ero okan re se ri lo

Oluwa ni kin so fun o wipe ota ko ni lagbara pelu anu olorun lati ba ojo ola awon omo re je

MO fi Olorun be o share adura yi si gbogbo group ori Facebook re ki ilekun anu ojo oni le si fun awon eniyan to ma ran aye re lowo nipase Facebook re

Iwo na te le wa lati te follow ko de like page ORIOKE ERIOBAALASEPE EMILERIKAN lati le gba itusile niun ajaga ogun ti ota de ile aye re si

Loruko Jesu pelu anu Olorun ati agbara to wa niun oro Olorun itusile lati odo Olorun ma de ba ile amin re loni

Amin share si 200 eniyan ki million eniyan pade anu olorun pelu amin re loni

23/07/2026

LORUKO JESU OFA IKU TABI AISAN KO NI BA O LORUKO JESU
SHARE SI GROUP META

23/07/2026

OLUWA KO SI IWE ANU KAN ILE AYE RE LONI

Address

Bojuri Adebayo Ado Ekiti
Ado-Ekiti

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Orioke Erioba Alasepe posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category