Ona Abayo Si Isoro Eda

Ona Abayo Si Isoro Eda WhatsApp number 09120815920

Akiyesi Pataki , Bi Iyawo re ba bi omo tuntun ma gbe Placenta omo re jusi Toilet , Nitori o lewu pupo , gbogbo omo tiwon...
05/10/2025

Akiyesi Pataki , Bi Iyawo re ba bi omo tuntun ma gbe Placenta omo re jusi Toilet , Nitori o lewu pupo , gbogbo omo tiwon ba gbe Placenta re jusi Toilet Ikorira maa po ninu Aiye omo naa , jeki ipile omo o re Dara, ki Adura re o Lee tete maa gba , bi Oyun Iyawo re bati pe OSU mesan Niki o ti ra ikoko kekere olomori , kio si rii daju wipe ninu OSU ti Iyawo re maa bi omo yi irinajo re o Jina sile, Nitori Iyawo re need most ni Ojo naa ,then Esekese ti olorun bati ni ki agbo ohun iya ti asi gbo ohun omo Niki o ti beere placenta omo re kio gbe sinu ikoko yan kio lo rii mole ,majeki enikeni mo ibiti ori placenta omo re mo, then rii daju wipe Iwo gangan o gbagbe location tio rii Placenta naa mo Nitori ojo iwaju , Ma gbe Placenta omo re fun family re tabi ore , ma trust anybody ni asiko yan ,, Then ni asiko tio ba fe ri placenta naa mole gbinyanju kio ka Qurisiyy iye tio bani agbara pelu Aniyan tio Dara, tio basi je Christian kio ka Sam ,,Nitori gbogbo Wahala ati idaamu ti opolopo wa face ninu irinajo Aiye wa ni oni , nio je wipe ojo tiwon ti bi wa tiwon ti gbe placenta wa fun olori ebi ni Wahala Aiye wa ti bere , then tio ba je Muslim ni e, tio ba fe fa irun ori omo re , ma gba anybody ni Aye lati ba e fa irun ori omo re , fa irun ori omo re funra re kio loo rii mole, ma da irun ori omo re si Toilet oh , Then ti eyin parents o ba tun fe ki awon omo ti olorun fun yin maa ba arawon se ota , leyin ti e ba bi omo tan tiwon si we omo naa tan , tiwon wa ni ki Mama fun omo ni Oyan , se Akiyesi Oyan tio ba koko gbe fun omo re , tio ba je wipe oyan otun nio koko gbe fun omo Alakobi , Oyan otun yan naa ni kio koko gbefun omo elekeji tio ba bi ati omo eleketa t**i ti waa fi bi omo tan , You want to breastfeed your new born baby for the first time , if you start with right hand breast for the first born if you born second born make sure you also start with the same right hand breast , pelu ase olorun ore ni awon omo re yio maa ba arawon se , gbogbo igba tio ba ti fun awon omo r

01/10/2025

5)Maje modaru eda ninu aye tabi ayekaye toba ba ara re, Bi oba ba ara re ni inu egbe kan tabi awujo kan, Maje kojepe iwo loma da egbe tabi awujo na ru, Iru awon eniyan be na o kini aseyori gidi lori idawole won.

6) Maje keeta tabi asebaje fun omonikeji re, Eda toba n se ibaje omonikeji re tabi oun se keta omonikeji re nibi ohun rere kan, iru won na kini ilosiwaju.

7) Bi oba wa ni party, tabi oloki yan, boya agbo faaji losi wa, sora lati mafi ohun to nje tabi mu sile dide loto tabi se ohun kan, tori a o mo eni ninu eni, a o mo eniyan ninu eniyan, Opo nati ti ipase iru nkan be je majele.

8) Maje onimo tara eni nikan, ti o ki bikita nipa ohun tole se elomi, ki ohun sati ri oun to n fe, Iwa ti o da ni iwa imo tara eni nikan.

9)Sora lati mani ibalopo pelu orisirisi okunrin kiri, Soro lati mani ibalopo pelu orisirisi obinrin kiri, Ole tibe ko orisirisi arun tole se akoba fun emi re, Bi oba ti e feni orekunrin tabi orebinrin, maje koju eyokan soso lo, Sugbon k**a ba orisirisi obinrin sun kiri, Ki orisirisi okunrin magun ori re, ohun to lewu pupo ni, Ma toripe oun wa oko, ki owa so ara re di ketekete fun awon okunrin.

10)Je eni tiyo mase akiyesi ilera ara re lorekore, Bi oba se akiyesi pe arun kan ti wole si e lara, tete se itoju re koto peju, Ma dagunla si ilera re, tori bi arun base n pe lara si, beeni yose ma buru si, Bi oba wati kefin arun kan lago ara re, tete se itoju re lasiko, koto dipe oma peju bose ye lo.

11)Maje odaju eniyan, je eleyinju anu ati oluranlowo fun omonikeji re, Bi enikan ba nilo iranlowo re, tosi ni agbara re, se iranlowo na fun, Tori eni to n bere fun iranlowo re loni, iwo na le nilo iranlowo ti e na lona, Kosi eni ti eniyan o le nilo iranlowo re, Olowo ama nilo iranlowo talaka, Torina maya odaju eniyan, mase iranlowo fun eni toba nilo iranlowo re, toba ni agbara re.

12) Sora fun sise modaru ohun ti won fi si e lowo, Bi enikan bafi ohun kan si e lowo pe koba oun se itoju re, Boya owo ni tabi nkan miran, Boya won si ko nkankan si ikawo re lati

01/10/2025

★★★★★★★★IRIN AJO AYE RE★★★★★★★
★★★★★★★★★ ★★★★★★★★
1) Sora fun adehun sise, adehun toba timo lokan ara re pe oni muse, ma wule se rara, Oto niki eniyan se adehun, kosi ni lokan lati mu adehun na se, Sugbon ki nkankan sele lati male jeki adehun na wasi imuse, Sugbon eni tose adehun, tosi timo lokan ara re pe oun oni mu adehun na se, Ota olorun ni iru won, Eni tose adehun fun pe oma fun ni nkan, tosi timo lokan ara re pe iro lo n pa fun eni na, Ota olorun ni e, Obinrin tose adehun fun pe oma fe, tosi timo lokan ara re pe iro lo n pa fun, Ota olorun ni e, Okunrin tose adehun fun pe oma fe, tosi timo lokan ara re pe iro lo n pa fun, Ota olorun ni e, Oro adehun sise kuro nipe mokan n se awada lasan, Ohun toba timo pe oni se, ma wule je koti enu re jade pe oma se, Oloselu to n se adehun tomo pe oun ole muse, lati leje ki awon eniyan dibo fun, Ota olorun ni iru oloselu be, Ohun kohun toba timo pe oni se, ma wule se adehun re fun eniyan, Ohun to romo adehun sise ni agbara gan ni, mase adehun toni muse fun eda egbe re mo.

2) Jibiti lilu ko yato si iwa ole, tori eni tolu ni jibiti, Ogba nkan to letosi lowo re ni, Eni to n lu jibiti, Iru eni be n pa elomi lekun jaye ni, Onakona ti eda legba lu jibiti ko oro jo, ofo loma n pada gbeyin iru won, Sora fun iwa jibiti lilu, toba n dara fun onijibiti ni osan, ale iru won ki sanmona, yera fun iwa jibiti nibi gbogbo.

3) Iwa okanjua, ojukokoro, omo iya kan na ni mejeji, eni toni okanjua tabi ojukokoro, iru won kini itelorun lori ohun tan bani, Biki gbogbo nkan di ti won ni, Iru won nama n joko te nkan oni nkan mole, Iru won nama n joko te ogun ologun, Iru won nama n ko ohun toto si eniyan bi mewa si apo ti won nikan soso, Igbeyin iru won kisi dara ninu aye, Oun tan fi ona eru kojo pada ma n pare mo won lowo ni.

4)Maje alaimore eda, je eni to mama mo riri oore ti enikan base fun, Eda ti o bamo iyi oore lati odo eda egbe re, Iru won kole mo iyi oore olorun oba, Je eni to mama mo riri oore ti enikan base fun e, maya

01/10/2025

★ÀLÁ TISE ÀLÀYÉ NÍPA ỌKỌ ÀTI ÀYÀ ÒRÙN★
★★★★★★★★★★★★★★★★★★★★★★★
Orisirisi ọna níí ala maùn gba waye sùgbón mẹta nani gbogbo ala

(1 Àkíyèsí ) ( ,2 ìkìlọ, ) ( 3 iranlasan)

Ọlọhun koni dáwà láàmú.

*ALA TOUN SỌRỌ NIPA ỌKỌ TABI AYA ORUN*

Bíi okùnrin ba lalá pé òun ni ìbálòpọ̀ oju òrun níí gbogbo igba ti osi ùn da s***m Sara leyin ti obaji tan
Ìtumọ:- ijakule níí àyà orun asima fi aayé gba ogun ìdílé sinu aiye ee mura síi oro aye e.

Bíi obinrin ba ùn lala pé okùnrin ti ko mọ ri ùn bá oun níí ìbálòpọ̀ loju orun ní gbogbo ìgbà leyin ti ojisi aiye oju ara rẹ ti tutu
Ìtumọ:- ọkọ òrun ni okunfa ogun eyi sile fa kii iṣẹ ọkọ ti ofẹ iru obinrin bayi síi ile mase ní ilọsiwaju

Bíi okùnrin ba lala wipe wọn fún oun ni ìyàwó loju ala
Ìtumọ:- aya orun níí eyii koni jeki ilọsiwaju wà fún irú enibe ati wipe oseese kii iru enibe mase ri iyawo fẹ loju aiye tabi koma ri idunu ninu igbeyawo e

Ema simi gbọ ó kìí se ọkọ ọrun àti àyà orun nikan lomaun fà Ibalopọ ojú òòrùn óo diẹ nínú àwọn nkọn tole fà Ibalopọ ojú òòrùn níyì
👇
Ogún ìdílé.
Egún ajogunba.
Awọn ari ogo síwájú ologo.
Bi Oba ni Ibalopọ s*x pẹlu ẹni ti ayé ti gbà ogo ara rẹ.
Asasi ọta.
Ìgbéyàwó òru.
Sísun ni ilana to lodi si iseda rẹ.
Wíwọ asọ totako kádàrá rẹ sún. E.t.c

Ìdí níyì ti mofi maùn sọ fún wà wípé ti abatiun ni Ibalopọ ojú òòrùn ìgbésẹ àkọkọ ni wipe ki akoko lọse Iwadi lórí ọrọ ayé wà ki ama baa ma fi òògùn inú rirun wò ori fifọ

Torí wipe eyikeyi tobawu kojẹ ogún to lagbara nínú ayé ẹdá ní sùgbón solution sì ọkọọkan bí Mósè kàà kalẹ yi ọtọọtọ ni.

Ọrọ pọ lori Ibalopọ ojú òòrùn topic yi lokan gbemi yà sibẹ̀ diẹ

*NKÁN TII ỌKỌ TABI AYA ORUN MA UN FA SINU AIYE ẸDA*

okunrin ti aya orun ba ùn da láàmú iru wọn kii ùn ri obinrin fẹ tobasi ri obinrin fe kole ri idunu ninu igbeyawo e

Ọkùnrin ti aya ọrun ba un da lamu iru wọn kii níí akojọ lẹnu iṣẹ

Ọkùnrin ti Aya òrun ba ùn da láàmú iru wọn amubo àyà má ùn bawọn já.

Obìnrin tí ọkọ òrun ba ùn da lamu irú wọn kii ùn ri ibujoko ayo.

Obìnrin tí ọkọ

aseje asiribibo owo.tagiri kan eyin agric kan tabi eyin ibileao ge tagiri ye Lori ao Fi obe ra gbogbo inure ao Fi eyin o...
30/09/2025

aseje asiribibo owo.

tagiri kan

eyin agric kan tabi eyin ibile

ao ge tagiri ye Lori ao Fi obe ra gbogbo inure ao Fi eyin ororo kan si ao Fi ideri re de pada ao gbe sori Ina ao se tio ba jina tan ao you epo ara eyin ye ao shadura si ao je.

29/09/2025

★★★★★*AWON NKAN TI KII JEKI OGUN SISE LARA ENIYAN★★★★★★★★★★★★ ★★★★★★★★★★★★★★★★★★

Ti eni tose oogun fune koba wa ni ajegun tabi awan ise pabida lowo kete ti obati gbe ise yi kuro ni odo re wan ti baje moe lowo.

Idi niyi ti awa alfa, pastor, baba alawo
Fi gbogbo wa ijinle agbara koto di wipe ao sowipe afema se aajo tabi gba awan eniyan sile

Iwo alfa, pastor baba alawo toun se deliverance fun awan eniyan tikowa si enikan towa give testimony ri definitely aye tie gan need deliverance.
AWON AJE… Ti awon agba ba nda eniyan laamu, irufe eni bee koni tete ri ona lo ninu aye koda ki iru enibe maa fi owo ti koni iye se oogun,

Awon aje pe orisirisi, aje pupa wa, dudu wa, funfun naa si wa. Aje idile wa , aje adugbo wa, aje ninu iyawo tabi ninu awon girlfriend. Awon agba si maun nda awon atorise laamu nigba ti won ba ntu eran ti won so mole.

Nje oogun toti e ran awan aje yi wa gan? hummm this is another topic eyin ololufemi esa maa fi adura ran mi lowo kin ri emi gigun ati alafia ara fi jise ti olohun ran mi siyin.

Modupe lowo gbogbo eyin ti eun fi emi imoore hon lori nkan ti moun se yi oluwa ama bami gbeyin lowo soke amin.

إنا لله وانا اليه راجعون😭😭😭😭…………الله اكبر ! الله أكبر !! الله اكبر !!!What a great loss to Islam entirely a giant and un...
06/12/2024

إنا لله وانا اليه راجعون😭😭😭😭…………الله اكبر ! الله أكبر !! الله اكبر !!!
What a great loss to Islam entirely a giant and undisputable scholar of our era returns to his creator sheikh muyideen ajani bello may almighty Allah accept your return and grant him highest place in jannah…Amin

04/12/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Gbenga Oyepitan, Godspower Obua

If u want any spiritual materials or u want to treat urself by native medicine chat me up any type of sickness I will tr...
22/11/2024

If u want any spiritual materials or u want to treat urself by native medicine chat me up any type of sickness I will treat u thanks

9 SPIRITUAL PERFUMES OILSU SEE THESE THREE SPIRITUAL PERFUMES OIL Eeh... U better don't joke with themDON'T UNDERSTATEME...
22/11/2024

9 SPIRITUAL PERFUMES OILS

U SEE THESE THREE SPIRITUAL PERFUMES OIL Eeh... U better don't joke with them

DON'T UNDERSTATEMENT THEM

VERY POWERFULLY

BOTH SPIRITUAL, PHYSICALLY, MENTALLY, AND OTHERWISE

I WILL POST THEIR WORK TOMORROW

STAY TUNE‼️




Address

No:8 Ajosinsin Compound Ede
Ede
323101

Telephone

+2348130902022

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ona Abayo Si Isoro Eda posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ona Abayo Si Isoro Eda:

Share