27/08/2025
--WlHT--ONE--MAN.....
Maso ara re di ketekete fun awon okunrin , duro pelu okunrin kan, lotito nini Ibalopo lasiko toye nse ago ara obinrin ni anfani
* O ma n je ki ara obinrin ma rewa si, awo re maje jade,yosi ma fresh,
* O ma nmu adinku ba ifunpa giga
* O ma nje ki nkan osu ma wa dada bo se ye
* O ma nje ki opolo ji pepe
* O ma n mu obinrin bu sara
* O ma n dena Arun jejere oyan fun obinrin
* O ma n dena awon aisan pepepe lago ara
* O ma n je keyan sun dada
* O ma boost hormones system ara
* O ma n jeki okan pumple eje si ago ara dada ti isan ara si ma wa free
Bi o ba wa fe ki Ibalopo mase gbogbo awon anfani timo ka sile yi lago ara re, okunrin kan lo gbodo maa gun ori re ,toba tidi pe orisirisi okunrin ti n gun ori re ,iru obinrin be koni pe dara nu, iru obinrin be koni pe gbo, iru obinrin be koni pe sa lawo,ka tie wa ni osi nile oko gan, iyen o sope ko so ara re di ketekete fun gbogbo okunrin, toba le mara duro ,gba okunrin kan laye ninu aye re,mafi nini Ibalopo pelu orisirisi okunrin so ara re di idakuda...
--Advice